Ajọkẹ Joshua jẹ ọmọ bibi inu Pasitọ T.B Joshua ti a ko mọ pupọ nipa iya to bi i. Arabinrin Evelyn ti i ṣe opo T.B Joshua bayii lo tọ ọ dagba, ọmọ ijọ to loyun fun Joshua lo bi Ajọkẹ ni ohun ti a ri.
Bi a ba ku laa dere, eniyan ko sunwọn laaye. Isin idupẹ waye ni ijọ Synagogue Church of All Nations, SCOAN lẹyin isinku oludasilẹ ijọ naa, TB Joshua. Lara awọn ojiṣẹ Ọlọrun jankan jankan to wa nibi ...
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results